Yoruba ni asegbe kankan ko si, asepamọ lo wa. Idi ree ti asiri se tu nipa eeyan meji to jade laye lasiko ti awọn osisẹ ọtẹlẹmuyẹ DSS se ikọlu sile asaaju ajijagbara fun ilẹ Yoruba, Oloye Sunday ...
Lẹyin ti iroyin gbode kan pe ajọ eleto idibo ilẹ wa, INEC, ti buwọ lu iyansipo David Mark, olori ile igbimọ aṣofin Naijiria tẹlẹ, ati Rauf Aregbesola, gomina ipinlẹ Osun nigba kan, gẹgẹ bii Alaga ati ...